text
stringlengths
9
354
label
int64
0
1
Dánfó gbókìtì lórí afárá #3RDMB bí a bá ń lọ #Oworo, súnkẹrẹfàkẹrẹ ti bẹ̀rẹ̀ torí ìran @user @user http://t.co/wyCxYAn0Wi
0
RT @user: Nínú ọ̀sẹ̀ kan náà, ìròyìn ikú obìnrin kan ni ó jáde láti ilé-iṣẹ́ Amóhùn-máwòrán Gbogboògbò orílẹ̀-èdè Angola tí ó ní wípé…
0
Wọ́n níṣẹ́ laago ń ṣe kú, síbẹ̀, ẹni tí kò bá nà ní ìpèbí, kò gbọdọ̀ jọba. Àṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní í ni 'ni lára.
0
Òpó-iná mànàmáná jí i, ó sì ṣubú l'ógèdèǹgbé"""" ---- A ní ẹja kan, òjíjí là ń pè é, 'ohun tí ó ń jí (shock) ' ni ẹja yìí ni a fi pè é ní ẹja òjíjí. Gbogbo àwọn tí mànàmáná bá jí kọ́ ni ó máa ń gbé jù sọnù. #idahunsiIbeere140318 #Yoruba https://t.co/IxdQD7VTFn
0
Fimisile ooo Miosemon Oooo Omoge ... 😆😆🙌🏾🙌🏾 belindaeffah DOP: frameshot_ #yoruba #lifeofahustler #undeserving #movie https://t.co/f5uD2JTkvJ
0
Gbogbo ojú títì ló ṣú òkùnkùn biribiri. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn kan nsọdá títì. Àwọn ọkọ̀ míì ò ní iná lẹ́hìn. Òmíì dákú sójú ọ̀nà. #naija
0
Ọwọ́ epo lọmọ aráyé ń báni lá, wọn kì í ń báni lá t'ẹ̀jẹ̀ #owe #Yoruba
0
RT @user: @user rudurudu ti wo inu aye gbaa!!
0
Ahhhh afi igba ti awon agbofinro fi ibon gba Gomina ipinle Nijer ano Aliyu Babangida lowo ara ilu. https://t.co/iUGOo6C8fJ
0
Wẹ́ẹ̀tì ẹ̀; olóṣèlú ọmọ ẹgbẹ́ Dẹmọ; DPNC lọ́dún 1960. Ẹgbẹ́ alátakò dáná sun ilé rẹ̀ ní #OkeSokori lágbo-ilé aládìí. #Abeokuta #Nigeria
0
@user Ah! Ọlọ́run Ọba. Irọ́ pípa ti wá di ojoojúmọ ní #naija. Àwọn akóròhìn kàyéfì. Àbí báwo ni ọmọ èèyàn ṣe lè bí ẹṣin?
0
Se lori oro #OsunDecides2018 #OsunElection yi abi nkan mi wa ni be ni. @user eso fun Unku @user ki wan ye pe maaalu ni buoda nitori at je suya! https://t.co/NcyFltRf3C
0
Tí a bá ń sunkún...
0
Ejò tó múra ìjà...
0
RT @user: Akéréjùpọ̀n/ jàngbórúnkún/ rogbo-àgùntàn; fún làkúègbé, arọmọléegun àti àìsàn orúnkún. #Yoruba #Ewe #Egbo https://t.co/zth…
0
.@user @user @user A ò lo Ináa mànàmáná dójú àmì, ìyẹn ò sì ní kí Adámú yín ó máà mú ìwé owó iná wá. Ìyẹn ò rá a yín, àfi kí ẹ gba owó ìbànújẹ́. #KoSinaKoSomi
0
Ìtákún - Episode 01. A DEATH IN THE FAMILY. (SLIDE I) """"""""Ohun tó ṣe àkàlàmàgbò tó fi dẹ́kun ẹ̀rin rínrín, tó bá ṣe igúnnugún, á wokoko mọ́ orí ẹyin ni"""""""". #itakunthestory #itakunbygemini #aremogemini #yoruba https://t.co/covSIUU7CW
0
Ìpọ̀nrí ajá ò jobì, irọ́ ni wọ́n pa mọ́ ajá. #Owe #Yoruba
0
Èèyàn ò sunwọ̀n láàyè; ọjọ́ a kú là ńd'ère. #yoruba
0
Kò sí ohun tí ó kan ẹ̀sìn pẹ̀lú òwe, bí ẹ bá máa pa òwe, ẹ pa òwe, ẹ má yí ọ̀rọ̀ òwe padà láti tẹ́ ẹ̀sìn lọ́rùn. Èwo ni """"""""Ẹní yára ni Jésù ń gbè?"""""""" Àmọ́ ṣá, àìdúró wámúwámú ń'nú èdè abínibí l'ó fa irú àfojúdi bẹ́ẹ̀ sí àjogúnbá ẹni nítorí kò bójú mu pínìnpínpìn.
0
Àlùfáà Samuel Johnson lo ogún ọdún láti ṣe àkójọpọ̀ ìmọ̀ fún ìwé rẹ̀, """"""""The History of Yorubas"""""""". Ní ọdún 1899, Àlùfáà Johnson kó àkójọpọ̀ iṣẹ́ yìí ló fún ọ̀gá ilé iṣẹ́ òǹtẹ̀wé Gẹ̀ẹ́sì. Ṣùgbọ́n, àlọ iṣẹ́ náà ló rí, kò rí àbọ̀ rẹ́. https://t.co/4Q2YAJa97h
0
À ní àwọn kan nínú ìjọba ló ba ìbáṣepọ̀ ìṣòwò orin láàárín Fẹlá àti gbajúgbajà iléeṣẹ́ orin; DECCA jẹ́ ni Olúfẹlá fi kọrin I.T.T. #NiIranti https://t.co/WVMiy0vyuY
0
RT @user: @user ogogoro ma n da inu ru oo, o ma n je ki eje ru ko da raara #Kemika
0
RT @user: @user @user o doni fonfon a sun fonfon Awon ota mi won o ni ji Fonfon l'eta n sun O doni fonfon a sun fonfon.
0
RT @user: Kini anfani orogbo? A be koni a we, a je o tun koro, a tun fe fi igi e da ina sango ni omo iya owun ni.... @user
0
@user Ọkọ náà kò rí ojú obìnrin náà kí ó tó fẹ́ ẹ ni? Aláìmọ̀kanmọ̀kàn ni ọkùnrin náà, ki ní kan tí àwọn eléèbó ń pè ní 'melanin' ni kò sí l'ẹ́yin ojú Rísíká àtàwọn ọmọ rẹ̀. Bákan náà ni ó rí fún àwọn èèbó tí ó ní irú ojú aláwọ̀ omi aró báyìí.
0
Ẹni tó ńbẹ̀rù àti ṣubú, àti dìde á nira fún un. / Whoever is scared of falling will find rising pretty tough. [Nothing ventured, nothing gained; be bullish; be open to taking calculated risks.]~@user #Yoruba #proverb #SARSMUSTEND #EndPoliceBrutality
0
Kò sẹ́ni tí òṣùbá sàńdákátà tọ́ sí lónìí, a ò rẹ́ni tó gba ìbéèrè márùn-ún, àyàfi Fọlá Onílé-eré ní @user tó gba mẹ́ta. https://t.co/vclmxx007H
0
iya omo kilo fun omo re oun fi iku sere igi ibepe ti o le se lo ngun. Kwam1 - Omo Instrumental. I tried. Someone correct me 🤦🏾‍♂️ #Nigeria #yoruba #fuji
0
Kánkán l'ewé iná ń jó'mọ Iná yóò jó o yín pa Wàràwàrà l'ọmọ í t'oko ìṣíbọ̀ Ilé ò gbá ọ̀nà ò gbà á ní í ṣe ewé àháràgbá Ilé á lé e yín, ọ̀nà á nà yín Àtilọ àtibọ̀ kì í jẹ́ kí àgánrándì ó gbádùn Ìnira ni ti yín, ẹ ò ní gbádùn #EpeForOurGovernment
0
RT @user: @user o n fi oju di mi.... He downgraded me.
0
... IBON Nii N Sii Eni Paa ... EPE Kii Sii Eni Jaa ... #Yoruba. #OKAY.
0
Àwọn ọmọ Yorùbá ní ìlú kan ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjéríyà ti farígá sí gbogbo rògbòdìyàn ati wàhálá tí àwọn Fúlàni danran-danran fà. Wọ́n sì ń kìlọ̀ fún ṣe isẹ́ wọn. Ài jẹ́ bẹ́, nkan ma sẹlẹ̀. #Yorùbá 👉 Yorùbátv ẸGBẸ… https://t.co/1IxKR9rz6J
0
Enu dun rofo. ema je ki Shettima tan yin je, ti ijoba yin ba gbe mekunu awa lama polongo @user ati @user https://t.co/ZRDQxaFx5q
0
Àjàyí tó di Samuel Crowther, Adéṣínà tí wọ́n fún ní Remigo, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, ara àwọ́n tí òwò ẹrú oníhá-mẹ́ta gbé lọ #RememberSlavery
0
@user Ǹ jẹ́ 'tí gbọ́? @user sọ pé ẹṣin inú ìwé lásán-làsàn ni yín... Ṣé lòótọ́ ni? Òkóbó ni yín?! #BankWars #Yoruba https://t.co/dcgKqUCKe5
0
Ikú pa abírí, abírí kú. Ikú pa abìrì, abìrì r'ọ̀run. Ikú pa Ọmọ Adú àtàtà, ó tún di ojú àlà. Sùn… https://t.co/JvC7DGa2Kg
0
@user @user Ọ̀rọ̀ Naija ló ṣú mi o jàre ọmọ ìyá.
0
RT @user: Ìpèníjà àti ìtanijí ńlá rèé fún ìran Yorùbá. Ọ̀jọ̀gbọ́n Karin Judith Barber, ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì àti oníṣẹ́ ìwádìí nípa à…
0
jọ, jagun. Àwọn ará Ìkòròdú fi ìdí wípé, ohun tí wọ́n fẹ́, bá ti Èkó lọ. Àti wípé, pàṣán tí àwọn Ẹ̀gbá fi na àwọn Oníṣòwò Èkó, ta bá àwọn náà ní Ìkòròdú, tí ìdáwọ́dúró ìtajà wà, látàrí ìjà tí àwọn Ẹ̀gbá ń gbé ko àwọn Oníṣòwò lójú.
0
Asiko ko dẹrun fun minisita fun eto iṣuna lorilẹede Naijiria, @user lọwọlọwọ pẹlu iroyin kan to n ja kaakiri bayii pe ayederu ni iwe ẹri agunbanirọ ti o n gbe kiri. - NYSC: Kẹmi Adeọṣun ń rì sínú ọ̀gbun ayédèrú ìwé ẹ̀rí https://t.co/Xj5OtpAhfP
0
Látorí àṣà 'kú/ẹ kú' tí àwọn ọmọ ìyá wa tó lọ sóko ẹrú nílẹ̀ Amẹ́ríkà ni a fi sọ ìran Yorùbá ní Akú. #ku #oku #eku #aku #ikini #Yoruba
0
RT @user: Ìjọba ìgbàlódé ń bá ìjọ ọba àdáyébá. Kò yẹ kí èyí ó wáyé rárá àti rárá ni. Àwọn ará ibí kàn ń sọ ìṣẹ̀ṣe di yẹpẹrẹ ni. Ó máà…
0
Owó tí o ba ti niye, abuku ti kàán #OweYoruba
0
Àwa ènìyàn dúdú pàápàá bẹ̀rẹ̀ sí í bára wa jagun, a sì í ńtara wa lẹ́rú fún èèbó nítorí owó. #Independence53
0
À rí ìgbọdọ̀ wí, baálé ilé sú 'ápẹ. #EsinOro🐎 #Yoruba https://t.co/anobpLUBqi
0
Ó ga o! Ọ̀gá #StellaOduah kílódé? Kí lẹ fẹ́ fi ọkọ̀ olówó iyebíye bá'un ṣe? Ta lo ṣẹ̀? #255millionnairabulletproofcars #Nigeria
0
Gbogbo ilé-iṣẹ́ wa wá di gbájúẹ̀. Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ ò dún dé ọ̀dọ̀ ẹni a pè, àmọ́ wọ́n yọ owó fùkẹ̀ lápò wa. #glo #mtn #Etisalat
0
Ni òwúrọ̀ kùtùkùtù ọjọ́ kan, ó tọ́ ìyá-a rẹ̀ lọ láti ṣ'àlàyé ọ̀ràn náà tí ojú-u rẹ̀ ń rí nílé ọkọ. Ó sọ fún ìyá-a rẹ̀, wípé ọ̀rọ̀ ọkọ òun ti sú òun, wípé òun kò leè farada ìhùwàsíi rẹ̀ mọ́. #MajeleToNPaOkunrin #Yoruba
0
Ara àntí ò yá Ara àntí ò yá Ìkọ́kọrẹ́ ń wọlé, abọ́ ń jáde. This should cure my body ache 🤔 🤔 Ọmọ #Ìjẹ̀bú èmi n wà https://t.co/j3BQLqXObk
0
Ilé tí a f'itọ́ mọ; ìrì ni yóò wó o. *Báwo ni ilé tí a fi itọ́ ẹnu mọ ṣe fẹ́ dúró sánsán? Bí ìrí bá ṣẹ̀, ó di gbàgà! #EsinOro🐎 #Yoruba
0
lábẹ́ Ọ̀gbómọ̀ṣọ́. Gbọ́n'mi si, omi ò tòó kan ṣẹlẹ̀ láàárín Tìmí Ẹdẹ àti Kakanfò Ọ̀gbómọ̀ṣọ́. Ohun tó fà áwọ̀ yìí, kò fojú hàn. Kakanfò fi Ẹdẹ ṣí Ẹtù tí Kìnnìún kò gbọdọ̀ ma ṣ'ọdẹ rẹ̀. Ni ó bá fi ìjà náà lé Lásinmi, tíì ṣe Balógun rẹ̀ lọ́wọ́, láti
0
1. Àwọn ará ibí yìí mọhun tí wọ́n ń ṣe o, bí wọ́n fún-un yín ní kọ́bọ̀ kí wọ́n tó wọlé, Náírà ni wọn yó fi kó bí wọ́n débẹ̀ tán #Abameta
0
Ìgárá ọlọ́ṣà gba ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ RBC 212 DE HONDA ACCORD SILVER COLOR 2012 ọ̀rẹ́ẹ̀ mi ní Ọ̀bà-Ilé. @user @user @user #Ondo
0
Ohun tí wọ́n gbé sí alákọrí lórí nìkan ló mọ̀, ó rò wípé a ò tí ì máa ka ọjọ́ kí ọlọ́ṣà tó ó dé. #OsuLe #Yoruba
0
@user: “@user: Ẹbọ ní ńpa ẹlẹ́bọ...”èpè ní ńpa elépè""""♣
0
RT @user: ✅Ọ̀bẹ ń wó ilé araa rẹ̀, ó ní òun ń ba àkọ̀ nínú jẹ́. ✅Àdá l'ẹnu tálákà, igbó la ó fi dá. ✅Bí ọwọ́ ẹni ò bá tẹ èkù idà, k…
0
Kukuru bilisi. Emo wo ilu Ado Ekiti Gomina lola @user ya igbaju gbigbona lu adajo ni Kotuu. Fayose wipe ohun ba adajo da apara ni..
0
@user hahaha. ó di dandan. Àyàfi ti èèyan bá fẹ jẹ̀jẹkújẹ kú lókù :)
0
RT @user: Ohun t'ó wá jẹ́ ẹ̀dùn ọkàn fún mi ò ju pé, @user tíí ṣe ọ̀kan lára ohun èlòo @user ńkọ iyán @user kére. #blogger…
0
Awọn ọna Meji - Apá 6 """"""""... Ẹniti o ba gba a gbọ ko ni da lẹbi; ṣugbọn ẹniti ko ba gba a gbọ lẹbi tẹlẹ, nitori ko gbagbọ ni orukọ Ọmọ bíbi kanṣoṣo ti Ọlọrun."""""""" Johannu 3: 16-18 #Ọlọrun #Jesu #EmiMimo #Bibeli #niife #Igbala #amojukuro #yoruba #Ioruba
0
Awon Adajo Ekiti ti dase sile o! Wan ni ewun be pelu awon jandukun ti @user ko dasi igboro. Kunmo ati Ada ti kun igboro Ado
0
Oro odun lenu ole, se odun 2016 ni David Mark mo ono Agatu. Lati odun ti wan fi un pa ara won, Mark de fila mawobe https://t.co/UFcFMLSyPS
0
Ará Èkó ò mọyì ará oko - (Those in Lagos; urban, no not the value of those in the farm; village, rural) #owe #yoruba #proverb
0
Ọ̀gá fi ọgbọ́n àrékérekè ọwọ́ wọn ba ti wa jẹ́, àmọ́ kò yé ọ̀pọ̀lọpọ̀ wa bẹ́ẹ̀ ẹni ire la pè wọ́n, ẹni ègbé ẹni ẹ̀tàn ni wọ́n. #Yoruba
0
Ó ti dójú ẹ̀ kí ọlọ́pàá ó máa ná owóo mọ́tò. Kódà ó bẹ̀bẹ̀ san ₦100 ni, kí àwọn ó jọ pín in ní fífítí fifitì. Kòró ká apá ẹ̀fíríbọdì, títí kan àwọn aṣebíológun àti ológun tí kì í fẹ́ sanwó ọkọ̀ l'Ékòó. https://t.co/PREdG5KbUj
0
RT @user: E kaaaro o. Emi ke? Bawo la se pin itan elede kan Lemoomu o? RT @user: @user Ẹ ... http://t.co/eXe204dJ7z
0
RT @user: """"""""Kòkòrò tí ń j'ẹ̀fọ́, ara ẹ̀fọ́ ló wà."""""""" Translation: """"""""The insect destroying a plant is on the plant."""""""" Lesson: Most e…
0
#iroyin, #yoruba, Odaran ni Matthew yii o ! O si tun fee dogbon gbe igbo wole fawon elewon… https://t.co/9J0UF1OuqC
0
Gbogbo èèyàn oníwà tùtù kọ́ lonínúure. / It's not everyone with quiet disposition that is kind natured. #yoruba #proverb
0
RT @user: @user @user Side apejuwe eniyan bi eni ti ko data tabi alaidaa eniyan
0
Agbako! Wan ti pa omo Gomina ano DSP Alamieyeseigha ni Dubai o! Alamieyeseigha ti je gomina ipinle Bayelsa ri. Osi je osafofin Ilu Oba (UK)
0
RT @user: @user Bo pe, bo ya esan nbo wa ke fun awon ojelu jegudu jera. E ni gbebu ika laiye, omo won je awon na aje pelu.
0
Èèmọ̀ pẹlẹbẹ rèé o, àfi bíi òkú àkúfà, ẹbí, ọ̀rẹ́ àti àwọn ẹniẹlẹ́ni agbóòkú #MIC ló tún forí kóo. Ó di gbére #RIP #AssociatedAirlineCrash
0
RT @user: @user. E wo nise ni mo nla gun be eni ti won ribomi. Ko si ina. Jenareto gan o wulo mo. Ilu ti dojuru. Oba Ed ...
0
RT @user: Ìgbin tó wá ẹ̀jẹ̀ lọ sí ilé alákàn, bó ti wọlé ni yóò padà jáde. / Any snail that goes to the crab's burrow in search…
0
Orí bíbẹ́ ni fún àwọn tí wọ́n rú òfin. Aníwúrà jẹ́ olórí alátakò fún Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò, Ààrẹ Látòòṣà. Ààrẹ Látòòṣà kọ ẹ̀yìn sí ìwà aburú Aníwúrà sí àwọn ẹrú rẹ̀. Ó sì ráńṣẹ́ pe Aníwúrà ṣùgbọ́n Aníwúrà kọ etí ikún sí ìpè náà.
0
RT @user: """"""""@user @user Okonjo-Iweala tan awon omo Naijiria lasan ni lori oro oko owo – Omo ile Asofin... http://t.co…
0
Ogún t’ó ja ìran Yoòbá lọ salau. Ọ̀tọ̀ ni ogun fọkọ̀, -fàdá, fidà, fi gbètugbètu jà, kí ó tó di fìbọn àti àgbá jagun. #AareOnaKakanfo
0
Aṣèbàjẹ́ ò ní gbayì.
0
RT @user: Tèmi ò ṣòro, tí kì í jẹ́ kí ọmọ alágbẹ̀dẹ ní idà. / Mine is not an issue, is how a blacksmith ends up not making a swo…
0
Àgbà ò sí ìlú bàjẹ́, Áwò kú, a gbàgbé ìlànà tí ó là á lẹ̀, a ò rántí bí ìṣàgbẹ̀ ti fa orílẹ̀ èdè Nàìjíríà sókè níjọ́hun àná. #IjoOle
0
Ọ̀jẹ̀lú kú ọ̀jẹ̀lú kù. Iná kú ó f'eérú bojú. Olè kú ó fi jàgùdà rọ́pò. #naija
0
Egbe Oselu UPN ti yo apoti ni idi Oludari Dokita Frederick Fasehun! Wan ni wipe onijekuje ni Dokita Fasehun. Ogbeni Manzo ni Oludari tuntun
0
RT @user: """"""""@user @user Egberun lona ogoru omo ogun kole bori wahala ile wa– COAS >http://t.co/oXjNdFb9YM
0
Balógun; baba-ní-ogun =► general {'ọfà ogún' ni balógun gbà s'ára -~- the general took '20 arrows' in the body} #InYoruba
0
Iro ni wan pa mo Oko mi o! Ore lasan ni Dame Jonathan ati Dotun! Iyawo Dotun Olusi kigbe nipa awuyewuye to gba igboro http://t.co/WpwCFqoLUN
0
Àb'ẹ́ẹ̀ rí i pé nkan ti wá dojúrú báyìí?
0
B'ẹ́nìkan ń yọni lẹ́nu, ẹni à ń yọ lẹ́nu á ní 'ṣé wọ́n bí ṣómi mẹ́ja ni?' @user @user @user @user @user
0
Ẹ ní n máà ṣépè, àmọ́ ó tó bẹ́ẹ̀, ó jù bẹ́ẹ̀ lọ. Bí a ò bá ti ẹ̀ fi wọ́n ré, wọ́n ti fi ara wọn ré. #IjobaWaKala #Nigeria #Yoruba
0
RT @user: L'ana, ọjọ́ Ìṣẹgun, ènìyàn tó ní àrun #coronavirus ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ igba ati m'ọkan-le-l'ọgorin, àjọ NCDC lo s…
0
... IWA Ibajee Waa Tiii Dii ASA ... Koo Tii E Sii ITIJU Moo ... #Omo #Yoruba. #OKAY.
0
Ẹ̀lààsòdè. Mo ti àṣẹ Èṣù bọnu. Ọ̀ràmfẹ̀, fi àrìrá rẹ sán pa wọn, gbogbo àwọn tí kò fẹ́ kí àwọn ọ̀dọ́ ó gbérí, àwọn tí kò fẹ́ kí Nàìjíríà ó tòrò. Ṣàngó Olùkòso, fi igba ọta bá wọn l'álejò. Àṣẹ!!! @user @user @user @user
0
Oju lari; ore o denu.......
0
Apa keji 🎼🎼🥁🎹🎺🎸🎼🎷🎺🎸🥁 Aje kun iya ni'oje, aje kun iya ni'oje, eni ti o t' eni no, t'on de na de ni, aje kun iya ni'oje https://t.co/qUyz8WN3tZ
0
RT @user: @user Tí ìṣẹ́ ò bá jẹ́ ká sọ òdodo, àìṣòdodo kò ní jẹ́ ká bọ́ lọ́wọ́ ìṣẹ́. / If fear of poverty makes us lie,…
0
RT @user: Wọ́n dá obìrin sí, wọn pa ọkùnrin? Ó ṣe jẹ́ ọkùnrin nìkan? Ọ̀ràn ńlá rè é, ó fẹ́ ìwádìí tó kúnrẹ́rẹ́. #BokoHaram #YobeMassa…
0
RT @user: Ní déédéé agogo méjì ọ̀sán òní, ní ọdún-un 1897 ni àwọn ọmọ ogun #Britain 1,200 ya wọ Ilẹ̀ Ìbíní, tí wọ́n sì falẹ̀ ya. Àwọn…
0
Kí ẹ dákun bá wa rí sí ọ̀rọ̀ ináa mànàmáná o, ìfàsẹ́hìn ló ń mú bá wa. @user #Nigeria
0
Májẹ̀ẹ́kódùnmí #MajekFasek ní irọ́ funfun báláú ni pé àrùn tí ò gbóògùn ló pa Abàmì-ẹ̀dá. Ó ní Abacha ló pa #Fela. @user
0