text
stringlengths
9
354
label
int64
0
1
Láfikún, ètòo nì bùkún iṣẹ́ ìdàgbàsókè ìlú tí ń gbèrò láti ṣe ìgbélárugẹ jíjẹ oúnjẹ aṣaralóore nípasẹ̀ sísè. Wàyí mo pe ọ́ 'níjà: jẹ́ kí a máa s'oúnjẹ?!
1
@user Team A lo mu igba oroke ni nu ere basketball ti gbogbo irawo ni Zenith Bank League fun awon obinrin. 🏀😁👍 #TweetinYoruba #ZenithWBL
1
@user Òtítọ́ ni. Àmọ́ àdúrà náà làá máa gbà fún un gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́ran-ara bíi tiwa
1
RT @user: """"""""M.K.O ọmọ Yorùbá rere, sun re o!!! Ẹ kú iṣẹ́ o @user, @user ṣàduà pé kí ọjọ́ yín ó dalẹ́. Àṣẹ http://t.co/GVWFLTI…
1
Yoruba kasahorow - Ẹti. Ẹrẹna 2, 2018: Ọdun titun dun! https://t.co/iCXi1Mteui #yoruba
1
Ìgbà ìpọ́njú là ń mọ̀rẹ́. Ẹ jẹ́ á ran 'ra wa lọ́wọ́ torí èní la rí, kò sẹ́dàá t'ó mọ̀la #Yoruba
1
RT @user: Amin. Beeni yii o ri fun wa """"""""@user: Òyígíyigì Ọlọ́run Àìnípẹ̀kun Ọba Alágbára ni èmi sá di lónìí. A jẹ́ pé ìbẹ ...
1
Èèyàn ò lè r'írú ọbẹ̀ yìí Kẹ́nu ó má po itọ́ láíláí. Háà! Ń ó jàkàṣù ẹ̀bà mẹ́fà. Bó sì jẹ́yán funfun lẹ́lẹ́ ni mo rí. N ó jẹ tó mẹ́ta bí ò bá tóbi jù. Àgàgà kí n r'ọ́kà tó fẹ́lẹ́ bí etí Àbí láfún to ń yọruku lálálá. https://t.co/joi01UyfCa #Atelewo #Yoruba https://t.co/crkVhmY6yc
1
@user: @user @user Mo ferun bi eshen lo ede yoruba lati so fun awon eyan nnkan ti o selee ni adugbo yin. E ku ise""""
1
RT @user: Oju adan o'nribi, oju awodi o'nri oran, loni ojo Aje ire loju wa yi'o ri. Gbogbo omo kutuojire eku ojomo Oo°˚˚˚°!
1
a tú dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn alátakò wá náà, a ó gbọn tán bẹẹni a ó mọ tán, a ń gbìyànjú ni, a ó sì ní rẹ̀wẹ̀sì láti tún moose si, laipe yii a ó gbé àmì idanimo wá jáde fún gbogbo yín. https://t.co/LEqsIFKqsR
1
Ẹní tó làná, tó lòní, kò leè lọ̀la; Ọlọ́run nìkan ló lọjọ́ gbogbo / Whoever called the shots yesterday and calls the shots today, cannot call the shots tomorrow; only God calls the shots at all times. [Nothing lasts forever; change is certain; keep up hope]#Yoruba #proverbs
1
My God is """"""""onise iyanu"""""""" ( A Miracle Worker) #yoruba
1
RT @user: Ẹ wá ba mi re! #yorubafood #naijafood #africanfood http://t.co/T32HYEPg4M
1