text
stringlengths
9
354
label
int64
0
1
RT @user: Kò sí ohun tó pọ̀ tí kì í tán, àfi ọlá Ọlọ́run. / Nothing, but the grace of God, can be so much in abundance and not…
1
RT @user: Ká panupọ̀ lé ẹlẹ́yọ́rọ́ lọ ná, kí a tó wá fàbọ̀ sí adìyẹ. / We ought to come together to chase away the fox first, b…
1
Awa omo Odua tooto ko ni boju wo eyin lati maa se agbelaruge ede Yoruba,nitori omo Kaaro-oojiire ni oriki ti o ni itunmo tio yaranti"""" Fatai
1
Ona lo jin, eru ni baba. #proverbs #Yoruba
1
@user Inú mi dùn kọjá ààlà :))
1
@user Ẹ má dáwọ́ iṣẹ́ dúró, mo ti recommend ìkànni yín fún gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ mi
1
RT @user: @user Eku ojumo o, #TweetYoruba ni @user
1
Kí o tẹ́tí kí o gbọ́, bó o bá fẹ́ gbọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì dáadáa, ìwọ lọ mọ èdè abínibíi rẹ dáadáa. #learn #yoruba
1
Ọlọ́run tó ńse'bẹ̀, kò tí ì kúrò ní ìdí ààrò. / God who is cooking the soup, has not left the kitchen. [Keep hope alive; never give up.] #Yoruba #proverb
1
Kó dùn, kó pọ̀, kó pẹ́, Ọlọ́run ló ńfún'ni. Photo Credit: Wale-Lanre shot https://t.co/kOcLVvGD5h
1
@user I hope you are fine brah Débọ̀? Ẹ pẹ̀lẹ́ o
1
Ẹ kú òwúrọ̀ o. Ọjọ́ ayọ̀ ni o.
1
Kò sẹ́ni tó dàbi i rẹ̀ láyé àti ọ̀run. Ọba Alágbára tí ndarí oun gbogbo. Ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ létí òkun pupa. #Olodumare #Olorun
1
Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, Agbẹnusọ, Mudasiru Ọbásá ní bí a bá wo ìlú tí ó ń sọ èdè abínibí lágbàáyé, a óò rí ìlọsíwájú t'ó ti bá wọn. #Yoruba #SKKY
1
Ojú ọjọ́ mọ́n kedere. Oòrùn ràn kalẹ̀. Àwọn ẹyẹ nkọrin. Afẹ́fẹ́ tútù nfẹ́. Ìfọ̀kànbálẹ̀ wá káárí ìlú. #oluwaseun
1
RT @user: Omo Atiba.. Adebayo Faleti.. Baami sunre ooo. Eiye odede ba loru le.... oro ni eiye ngbo..... #yoruba #actors #theatre
1
@user: E ku asiko yii @user, e si kuulu yii. Oosa oke o ba wa se gbogbo ohun ta n fe pata. @user"""" àṣẹ o.
1
Oriki mi ni Ayoka,abiso mi ni IYABODE abi mi ni adugbo kan ti an pe ni lawanson ni odun die seyin,eku irole,oodua a gbe wa #TweetinYoruba
1
RT @user: Eyi lo d'ifa fun Baba Ijesha to kigbe wipe """"""""wonderful l'Olorun ria, Onise uyanu ni Baba""""""""! RT """"""""@user: Ìyanu ni i ...
1
Ẹ kú ojúmọ́ o. Ìrìnàjò la wà. Ọba jẹ́ ká gúnlẹ̀ láyọ̀ o. #ekaaaro #irinajo http://t.co/LIUik9G3HY
1
Bí o bá fẹ́ 🧠 ọpọlọ t'ó jí pépé, bí o bá fẹ́ kí iyè rẹ ó máa là gààrà ńgbà 'ogbo, rẹ ewé ẹ̀là sómi kí o máa mu ú. #Ewe #herbs #Yoruba https://t.co/r15lUtJQ4t
1
RT @user: """"""""@user: Ẹ kú ojúmọ́ o. Èwo lẹ ṣe ẹ̀yin ẹ̀dá Olúwa? #ekaaaro"""""""" a se ti Oluwa, e kaaro o
1
Mó mà fẹ́rà ewì ọmọ tuntun yen o! Ó nwù mí kí èmi náà lè kọ irú ewì yí. Bóyá màá gbìyànjú ẹ̀.
1
RT @user: @user wa gbayi jare
1
Odídẹrẹ́ ẹyẹ òkun Àlùkò ẹyẹ ọ̀sà. B'ójú bá sé ojú, k'óhùn má yẹ ohùn! Ilé l'a ti í kó ẹ̀ṣọ́ọ́ ròde Ilé sì n'ìbọ̀yèé bọ̀ọ́ sí. Ẹ má mà jẹ́ k'á mọ èdè elédè Ju èdè ilẹ̀ẹ tiwa lọ. 3/4 #IdentityMatrix #Yoruba #EdeYorubaLoriAyelujara
1
RT @user: Ife bi eji owuro""""""""@user: Òjò ìfẹ́ rọ̀ lọ́jọ́ Olólùfẹ́ #Lagos""""""""
1
RT @user: Iyà l'olùgbowó mi tí n tójú mi ni kékeré... Eyìn re lo fi pon mí.... Èmi íkí 'ya mì kú 'sé.. Èmi kò lè ko'sé fún 'ya mì. ...
1
@user Oju wa ò ní fọ́ láṣẹ Èdùmàrè!
1
Àbùsíèdùmàrè The additional blessings of olódùmarè. https://t.co/82ZudUxt56
1
A kú òwúrọ̀ o :) #yoruba#Lagos#Ogun#Ife#Oyo#Ibadan#Osun#EkitiState#Ijebu#Benin#kwara
1
Ẹ múra síṣẹ́ o ẹ̀yin ènìà mi. Wọ́n ní iṣẹ́ níí múni di ẹni gíga. Òní ọjọ́ ajé, ẹ má fẹsẹ̀ falẹ̀ o.
1
Àwọn onígbàgbọ́ a máa ní """"""""má kọjá mi olùgbàlà kìí ṣ'orin àkúnlẹ̀kọ"""""""". Ẹni bá rí ore rẹ̀ tí nkọjá lọ, kó yáa dìde sáré tẹ̀lé e!
1
@user Àṣẹ Èdùmàrè 🙌🏾🙏🏽.. Culture before border... Ọmọ Yorùbá ni mí.. #tiwantiwa ti àkísà n t'àkìtàn.. #Oòduà #yorubasofsocialmedia #Yoruba
1
RT @user: Obo dupe dun ju dun dun lo o #TweetinYoruba #SambaSeason #Newsingle #comingsoon. 😉
1
Ǹjẹ́, ohun gbogbo t'ó bá ń dùn mí, n ó máa rò f'óríì mi. Oríì mi là mí o, ìwọ lalágbọ̀ràndùn.
1
Yorùbá adage for the week: """"""""Nínú oore l'oore wà"""""""". Translation: Kindness begets kindness What did you learn from this Òwe? #learnyoruba #wisesayings #owe #mondaywisdom #yorubalessons #yoruba https://t.co/6BcpKUKcBf
1
RT @user: Edumare Oba ma pa IYA MI L'EKUN @user AKU ODUN º°˚˚°º http://t.co/tsTLD4Ld7y
1
Iṣẹ́ tí àwọn wọ̀nyìí ṣe sílẹ̀ lọ́jọ́ ayé ló sọ wọ́n di ẹni tí ọmọ aráyé ń ké pè fún ìrànlọ́wọ́, ìmọ̀ràn tí wọ́n sí ń wóò láwò kọ́ṣe #orisa
1
RT @user: Kosi eni tole b'ogo orun mole""""""""@user: àfàìlà ojó, tójó bálá, màálà dandan. àfàìràn oòrùn, t'órùn bá ràn, èmi na a t ...
1
Èdè yìí ò ní kú. Kò ní parun láíláí. #TweetYoruba
1
Won ni yoruba ni won nso leni ni tuwita,ekale oo gbogbo ara ilu mi Nigeria ati agbaye lapapo.Se alafia ni #TweetInYorubaDay #TweetinYoruba
1
Iwájú lọlọ́kọ̀ yí nwà mí lọ...♫
1
Nijeria aku odun o! A gba ominira lowo awon alawo fun fun. Awa dudu wa hun gun ara wa bi esin. Koda oko eru Oyinbo wa da bi paradisee . #54
1
@user Amin o Eledumare ko ni je ki ona ki o di mo enikeni ninu wa
1
@user """"""""Mélòókan"""""""" ni mo wí o. Gbogboyín lẹ ṣe pàtàkì. :)
1
Báwo ni o @user, kú àbọ̀ :)
1
@user Ẹ̀hn!! toò. Ẹkú àpọ́nlé wa o! Àjọṣe ló dùn. :))
1
RT @user: Ti imú yé imú tí imú fi ńfọn. / The nose has its reasons for being noisy (when blown). [People have their reasons: giv…
1
RT @user: @user oseee o sese yemi dada niii
1
RT @user: """"""""@user: Láìsí ìrànlọ́wọ́ Ọlọ́run, ẹ̀dá kàn nsáré ká ni. Olúwa rànwá lọ́wọ́ o."""""""" L'oruko Jesu Olugbala wa, Amin.
1
Ologbon ton shebi omugo, oni bose je #Yoruba's
1
RT @user: Ẹ jẹ́ ká dúpẹ́ lọ́wọ́ @user tí wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ #tweetYoruba --> http://t.co/52eEZngdRg
1
@user @user @user @user @user @user @user @user @user O ṣeun omidan Folúkẹ́ fún ọ̀rọ̀ ìṣítí yìí, n ó fi s'ọ́wọ́ òsì, n kò ní fi jẹun.
1
Gbọgbọọgbọ lọwọ́ọ́ yọọ́ Jorí; gbọgbọọgbọ ni màrìwò ọ̀pẹ̀ẹ́ yọọ́ jọ̀pẹ̀; gbọgbọọgbọ ni ẹ̀ẹ́gun òkèèrèé yọọ́ jù wọ́n. N ó yọ jọ̀tá lọ. #Iwure
1
Ìfẹ là kọjá òfin. Ìfẹ máa ǹ fi ọkàn àwọn èèyàn dára. #yoruba #yorubas #quotes #NigeriaDecides2019 #Nigeria #yoruba
1
Ṣé pé @user ti ṣe ìṣàmúdájú òdigì ọmọ Kwárà; ojúlówó ọmọ #Nigeria @user? Ó da bẹ́ẹ̀.
1
RT @user: kirakita eda laye Olohun lomo. Oluwa se mi ni araba ti idi re duro gboin. Mo ga bii oke:inu mi dun;abuku o kan mi mo;mo kiyesi…
1
Kábíèsí Ọ̀rọ̀mpọ̀tọ̀, ọkùnrin ogun. #Oyo #Yoruba """"""""@user: https://t.co/4Tav6TMlqE""""""""
1
Mo jí mo jí o Baba, mo wa fi ọpẹ́ fún Ọ ...
1
@user - Ẹ kú iṣẹ́ #Yoruba #yobamoodua
1
♪ Òjò ni wá, a 'ò b'ẹ́nìkan ṣọ̀tá o ... ♫
1
RT @user: @user E ku ojumo. A kin bokurun eye lori ite.
1
Ọpẹ́lọpẹ́ ọmọ-ogun Ìbàdàn, ì bá má sí ọba aládé tó jẹ́ Yorùbá níbi kankan ńlẹ̀ káàárọ̀-o-ò-jí-ire mọ́. #ItanFulani #Darandaran #Nigeria
1
@user Ó kúkú kọ́ gbogbo wa lọ́gbọ́n ṣá. Ìmọ̀nràn tó dáa ni. :)
1
Ìwádìí fínífíní ti fi hàn wípé èròjà aṣara lóore omi inú àgbọn ò lẹ́lẹ́gbẹ́, omi àrà ni, omi ìyanu sì ni pẹ̀lú. #Yoruba #Agbon
1
@user Ẹ kú ìgbádùn o. Ọ̀dọ̀ tiwa náà dùn
1
Bẹ́ẹ̀ ni Ọmọ Ọba ... Ìwá ẹni ni àwúre ẹni #Orunmila http://t.co/3NuBo61j4M
1
RT @user: Mimo, Mimo, Mimo, Olodumare (Holy, Holy, Holy) #yoruba #JESUSlovesYOU https://t.co/UWc27IfjJD via @user
1
RT @user: Ẹní bá dúpẹ́ oore àná yóò rí òmíràn gbà. / Whoever gives thanks for yesterday's kindness, will receive another. [Attit…
1
Láolú ọmọyè mi, kú oríire ti àjọṣepọ̀ @user o. Òkè báyìí l'ẹmu ń ru sí. Mo bá ọ yọ̀ o """"""""@user https://t.co/bUJkV8irk9…""""""""
1
Ọjọ́ kejì ọdún tuntun; ẹgbàá-ọdún-ó-lé-mẹ́ẹ̀ẹ́dógún. Ẹ̀míì mi lá rí òpin ọdún un 2015 yìí, ọdún nìí ò ní rópin-ìn mi #Ase
1
RT @user: Ẹni òjò pa, tí àrá ò pa, kó máa dúpẹ́. / Whoever got beaten by rain but wasn't struck by lightning should be thankful…
1
Ede Yoruba ni aadun o ni arinrin. Ede to Eledua fi MBA omo araiye so oeo bu #TweetinYoruba
1
Ẹ káàsán o ẹ̀yin èèyàn mi. S'álàáfíà ni! Gẹ́gẹ́ bí a ṣe máa ń ṣe ń'gbogbo Ọjọ́rú, n ó máa túwìtì ìbéèrè Yorùbá, ká wo ẹní bá dángájíá jùlọ.
1
Ọlọ́run ṣàánú wa. Dáríjìn wá Olódùmarè. #adura
1
Òní lọjọ́ ìbí rẹ O kú àṣeyẹ Ẹ̀mí rẹ á ṣe púpọ̀ oó Happy birthday to our Gómìnà @user, Àṣèyí ṣàmọ́dún sir! https://t.co/T4YyoSBRPD
1
@user Ọba lókè jẹ́ ká gbọ́ran síwọn lẹ́nu.
1
Orun alẹ́ ònìí á yàtọ̀ :) #Ero
1
RT @user: Lẹ́hìn òkùnkùn biribiri, ìmọ́lẹ̀ á tàn. / After a pitch darkness, most assuredly comes the dawn. [No matter how it lo…
1
Kò lè burú títí kó má ku ẹnìkan mọ́'ni, ẹni tí yóò kù la o mọ. / Things can never be so bad that one will be left with no one, but who he or she will be is what one may not know. [Keep hope alive; you are never alone: it only seems so.] #Yoruba #proverb
1
Àdúrà mi sí gbogbo ọmọ O'òduà ní'lé, lóko, lọ́nà ní'rìnàjò ni wípé láabi ò ní kángun sí ilée wa, ẹsẹ̀ gìrìgìrì ò ní ya ilée wa fáburú
1
Beeni ti enia ba si ti ri oloro eni oluware yoo di sorosoro""""""""@user: Awo ti ri awo, olongini ti ri omo ekun,kajo ma se ere o • """"""""@user
1
Àṣe yè lalákà ń ṣ'epo. Ilé alákàn kì í gbẹ. Àṣe yè, àṣe yẹ, àṣe là, àṣe lówó lọ́wọ́, àṣe ṣooríre ni tiwa láyée wa http://t.co/vHXDH7Kd6U
1
@user awa niyen jare se daadaa ni e wa se gbogbo nkan n lo daadaa
1
@user wọ́n á jẹun ọmọ pẹ́ pẹ́ pẹ́ láyé. Yèyé abiamọ tòótọ́. #EkuOjoIbi
1
RT @user: @user O niise nipa ki awon agbaagba oloselu ile wa fun awa odo ni #IdaOgbon ninu ida Ogorun ninu isakoso ile Naij…
1
Jọ̀wọ́ rọra mu *Kẹ́míkà*
1
Ẹbọ́ fín, ẹbọ́ dà, Rírí fi inú ṣ'oyún, àṣẹ̀hìnwá, ó bí ọmọ mẹ́ta tí orúkọ wọn ń jẹ́, Ọjà, Ọ̀nà àti Ilẹ̀. #IgbagboYorubaNipaAje
1
RT @user: Ifipabanilopọ maa dinku bijọba ba ṣi otẹẹli ati ile-ijo - Olomide @user @user @user #sundayvibes https://t.…
1
@user ẹ jọ̀wọ́, ẹ tẹ́lẹ̀ wa padà
1
@user Iroyin Ayo . A ba obi awon Omo akeeko naa yo, won ku oriire na. Omo wa o Ni soonu #TweetinYoruba
1
Odídẹrẹ́ tí kìí kú s'óko ìwánkanjẹ, yó kó èrè oko délé.
1
Inú wa dùn láti kéde pé àwọn wọ̀nyí ni àkọ́yàn. Nínú wọn ni a ó ti yan àwọn márùn-ún tí yóò gbé gbá orókè nínú ÌDÍJE ÀTẸ́LẸWỌ́ FÚN Ẹ̀BÙN LÍTÍRÉSỌ̀ YORÙBÁ TI ỌDÚN 2021. Ẹ má bá wa ká lọ. A gbóríyìn fún gbogbo àwọn olùkópa. #AtelewoPrize #Yoruba #Atelewo #longlist https://t.co/Mk6JQy1AtU
1
RT @user: """"""""Today’s Yoruba Motivation! Ma gberu eleru sori ko o wa fa tire lowo,Take charge of your own life👍🏿 Abo oro.... Ayaworan mi:…
1
@user Èyí o wù ó jẹ́, akọ ìgbádùn nbẹ ní Ìjẹ̀bú Òde ọmọ ìya mi 😂
1
Mo wólẹ̀ o, Ọ̀gbẹ́ni Akínwùnmí Adéṣínà @user, mo kì í yín, mo kì yín. Bákan náà ni mo gbé òṣùbà sàńdákátà fún un yín fún àwọn iṣẹ́ kantikanti tí ẹ̀ ń gbé ṣe ní ti ìgbésókè Ilẹ̀-Adúláwọ̀. Ẹ sì kú orí ire ìyànpadà sípò gẹ́gẹ́ bí Ọ̀gá àgbà @user 👍🏿
1
Ẹ fún àwọn ìyá wa lọ́wọ̀. K'á yée f'ojú tẹ́mbẹ́lẹ́ẹ wọ́n @user #2030Now #Nigeria http://t.co/3x5M9PsGxx
1
RT @user: @user A dupe. Ope ni fun Oluwa ti o mu wa ri ojo to ni. Oni a san wa sowo, san wa somo ati alafia, Amin
1
RT @user: @user Àmín àse, àse wa ni t'Èdùmàrè
1
Àtiṣe pọ̀ jọjọ. Olódùmarè ràn mí ṣe, ìrànlọ́wọ́ọ̀ Rẹ ni mo tọrọ.
1